Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 26:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Yóo di ibi tí wọn óo máa sá àwọ̀n sí láàrin òkun, nítorí èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀; yóo sì di ìkógun fún àwọn orílẹ̀-èdè mìíràn.

Ka pipe ipin Isikiẹli 26

Wo Isikiẹli 26:5 ni o tọ