Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 26:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn óo wó odi Tire; wọn óo wó ilé-ìṣọ́ tí ó wà ninu rẹ̀ palẹ̀. N óo ha erùpẹ̀ inú rẹ̀ kúrò, n óo sì sọ ọ́ di àpáta lásán.

Ka pipe ipin Isikiẹli 26

Wo Isikiẹli 26:4 ni o tọ