Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:35 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA Ọlọrun ní, “Nítorí pé o ti gbàgbé mi, o sì ti kọ̀ mí sílẹ̀, o óo jìyà ìṣekúṣe ati àgbèrè rẹ.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:35 ni o tọ