Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:34 BIBELI MIMỌ (BM)

O óo jìyà ní àjẹtẹ́rùn,tóbẹ́ẹ̀ tí o óo máa fi àkúfọ́ àwo ìyà tí o bá jẹ ya ara rẹ lọ́mú.Èmi OLUWA Ọlọrun ni mo sọ bẹ́ẹ̀.”

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:34 ni o tọ