Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 23:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìkórìíra ni wọn yóo fi máa bá ọ gbé, wọn yóo kó gbogbo èrè iṣẹ́ ọwọ́ rẹ lọ, wọn yóo sì fi ọ́ sílẹ̀ ní ìhòòhò goloto. Wọn yóo tú ọ sí ìhòòhò, gbogbo ayé yóo sì mọ̀ pé aṣẹ́wó ni ọ́. Ìṣekúṣe ati àgbèrè rẹ ni

Ka pipe ipin Isikiẹli 23

Wo Isikiẹli 23:29 ni o tọ