Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 2:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí ó ti ń bá mi sọ̀rọ̀, ẹ̀mí OLUWA wọ inú mi, ó gbé mi nàró, mo sì gbọ́ bí ó ti ń bá mi sọ̀rọ̀.

Ka pipe ipin Isikiẹli 2

Wo Isikiẹli 2:2 ni o tọ