Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Isikiẹli 15:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí ó wà ní odidi, kò wúlò fún nǹkankan. Nígbà tí iná ti jó o, tí ó ti di èédú, ṣé eniyan tún lè fi ṣe ohunkohun?”

Ka pipe ipin Isikiẹli 15

Wo Isikiẹli 15:5 ni o tọ