Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 7:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní ọjọ́ tí ọba ń ṣe àjọyọ̀, àwọn ìjòyè mu ọtí àmupara, títí tí ara wọn fi gbóná; ọba pàápàá darapọ̀ mọ́ àwọn ẹlẹ́yà.

Ka pipe ipin Hosia 7

Wo Hosia 7:5 ni o tọ