Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 7:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n yipada sí oriṣa Baali, wọ́n dàbí ọrun tí ó wọ́, idà ni a óo fi pa àwọn olórí wọn, nítorí ìsọkúsọ ẹnu wọn. Nítorí náà, wọn óo ṣẹ̀sín ní ilẹ̀ Ijipti.”

Ka pipe ipin Hosia 7

Wo Hosia 7:16 ni o tọ