Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 7:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí mo bá fẹ́ dá ire Israẹli eniyan mi pada, tí mo bá sì fẹ́ wò wọ́n sàn, kìkì ìwà ìbàjẹ́ Efuraimu ati ìwà ìkà Samaria ni mò ń rí; nítorí pé ìwà aiṣododo ni wọ́n ń hù. Àwọn olè ń fọ́lé, àwọn jàgùdà sì ń jalè ní ìgboro.

Ka pipe ipin Hosia 7

Wo Hosia 7:1 ni o tọ