Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 5:14 BIBELI MIMỌ (BM)

Bíi kinniun ni n óo rí sí Efuraimu, n óo sì fò mọ́ Juda bí ọ̀dọ́ kinniun. Èmi fúnra mi ni n óo fà wọ́n ya pẹ́rẹpẹ̀rẹ, n óo sì kúrò níbẹ̀. N óo kó wọn lọ, kò sì ní sí ẹni tí yóo lè gbà wọ́n sílẹ̀.

Ka pipe ipin Hosia 5

Wo Hosia 5:14 ni o tọ