Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 5:13 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí Efuraimu rí àìsàn rẹ̀, tí Juda sì rí ọgbẹ́ rẹ̀, Efuraimu sá tọ Asiria lọ, ó sì ranṣẹ sí ọba ńlá ibẹ̀. Ṣugbọn kò lè wo àìsàn Israẹli tabi kí ó wo ọgbẹ́ rẹ̀ sàn.

Ka pipe ipin Hosia 5

Wo Hosia 5:13 ni o tọ