Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 2:18 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà náà ni n óo tìtorí tirẹ̀ bá àwọn ẹranko, àwọn ẹyẹ, ati àwọn nǹkan tí ń fi àyà fà lórí ilẹ̀ dá majẹmu, n óo sì mú ọfà, idà, ati ogun kúrò ní ilẹ̀ náà. N óo jẹ́ kí ẹ máa gbé ní alaafia ati ní àìléwu.

Ka pipe ipin Hosia 2

Wo Hosia 2:18 ni o tọ