Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 13:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Samaria ni yóo ru ẹ̀bi ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, nítorí ó ti ṣọ̀tẹ̀ sí èmi Ọlọrun rẹ̀, ogun ni yóo pa wọ́n, a óo ṣán àwọn ọmọ wọn mọ́lẹ̀, a óo sì la inú àwọn aboyún wọn.”

Ka pipe ipin Hosia 13

Wo Hosia 13:16 ni o tọ