Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 12:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Asán ati ìbàjẹ́ ni gbogbo nǹkan tí Efuraimu ń ṣe látàárọ̀ dalẹ́. Wọ́n ń parọ́ kún irọ́, bẹ́ẹ̀ ni ìwà ipá wọn ń pọ̀ sí i. Wọ́n ń bá àwọn Asiria dá majẹmu, wọ́n sì ń ru òróró lọ sí ilẹ̀ Ijipti.”

Ka pipe ipin Hosia 12

Wo Hosia 12:1 ni o tọ