Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Hosia 11:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. OLUWA ní,“Nígbà tí Israẹli wà ní ọmọde, mo fẹ́ràn rẹ̀,láti ilẹ̀ Ijipti ni mo sì ti pe ọmọ mi jáde.

2. Ṣugbọn bí mo ti ń pè wọ́n tó,bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n ń sá fún mi,wọ́n ń rúbọ sí àwọn oriṣa Baali,wọ́n ń sun turari sí ère.

Ka pipe ipin Hosia 11