Bẹ́ẹ̀ ni èmi ni mo kọ́ Efuraimu ní ìrìn,mo gbé wọn lé ọwọ́ mi,ṣugbọn wọn kò mọ̀ pé èmi ni mo wo àwọn sàn.