Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 1:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣé gbogbo ìgbà ni àwọn eniyan yóo máa bọ́ sinu àwọ̀n rẹ̀ ni? Ṣé títí lae ni yóo sì máa pa àwọn orílẹ̀-èdè run láìláàánú?

Ka pipe ipin Habakuku 1

Wo Habakuku 1:17 ni o tọ