Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Habakuku 1:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà a máa bọ àwọ̀n rẹ̀. A sì máa fi turari rúbọ sí àwọ̀n rẹ̀ ńlá; nítorí a máa rò lọ́kàn rẹ̀ pé, àwọ̀n òun ni ó ń jẹ́ kí òun gbádùn ayé tí òun sì fi ń rí oúnjẹ aládùn jẹ.

Ka pipe ipin Habakuku 1

Wo Habakuku 1:16 ni o tọ