Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 9:2 BIBELI MIMỌ (BM)

àwọn Juu péjọ ninu àwọn ìlú wọn ní àwọn ìgbèríko ilẹ̀ Ahasu-erusi ọba, wọ́n múra láti bá àwọn tí wọ́n fẹ́ pa wọ́n run jà. Kò sí ẹni tí ó lè kò wọ́n lójú nítorí pé gbogbo àwọn eniyan ni wọ́n ń bẹ̀rù wọn.

Ka pipe ipin Ẹsita 9

Wo Ẹsita 9:2 ni o tọ