Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsita 6:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n kà á ninu àkọsílẹ̀ pé Modekai tú àṣírí Bigitana ati Tereṣi, àwọn ìwẹ̀fà meji tí wọn ń ṣọ́ ẹnu ọ̀nà ilé ọba, tí wọ́n dìtẹ̀ láti pa Ahasu-erusi ọba.

Ka pipe ipin Ẹsita 6

Wo Ẹsita 6:2 ni o tọ