Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 9:6 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ọlọrun mi, ojú tì mí tóbẹ́ẹ̀ tí n kò lè gbójú sókè níwájú rẹ. Ìwà burúkú wa pọ̀ pupọ níwájú rẹ, àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa ní ìpele ìpele, sì ga títí kan ọ̀run.

Ka pipe ipin Ẹsira 9

Wo Ẹsira 9:6 ni o tọ