Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 9:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò ẹbọ àṣáálẹ́, mo dìde kúrò níbi tí mo ti ń gbààwẹ̀ pẹlu aṣọ ati agbádá mi tí ó ya, mo kúnlẹ̀, mo sì tẹ́wọ́ sí OLUWA Ọlọrun mi, mo gbadura pé:

Ka pipe ipin Ẹsira 9

Wo Ẹsira 9:5 ni o tọ