Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 6:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Lojoojumọ, ni kí ẹ máa fún àwọn alufaa tí wọ́n wà ní Jerusalẹmu ní iye akọ mààlúù, àgbò, aguntan pẹlu ìwọ̀n ọkà, iyọ̀, ọtí waini ati òróró olifi, tí wọn bá bèèrè fún ẹbọ sísun sí Ọlọrun ọ̀run.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:9 ni o tọ