Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 6:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ati pé, mo pàṣẹ ohun tí ẹ gbọdọ̀ ṣe láti ran àwọn àgbààgbà Juu lọ́wọ́ láti kọ́ ilé Ọlọrun náà pé: Ninu àpò ìṣúra ọba ati lára owó bodè ni kí ẹ ti mú, kí ẹ fi san gbogbo owó àwọn òṣìṣẹ́ ní àsanpé, kí iṣẹ́ lè máa lọ láìsí ìdádúró.

Ka pipe ipin Ẹsira 6

Wo Ẹsira 6:8 ni o tọ