Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 5:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Ní àkókò kan náà, Tatenai, gomina agbègbè òdìkejì odò ati Ṣetari Bosenai ati gbogbo àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn wá sí ọ̀dọ̀ wọn, wọ́n bi wọ́n léèrè pé: “Ta ló fun yín láṣẹ láti kọ́ tẹmpili yìí ati láti dá àwọn nǹkan inú rẹ̀ pada sibẹ?

Ka pipe ipin Ẹsira 5

Wo Ẹsira 5:3 ni o tọ