Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 5:2 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Serubabeli, ọmọ Ṣealitieli ati Jeṣua, ọmọ Josadaki gbọ́ ọ̀rọ̀ wọn, wọ́n bẹ̀rẹ̀ sí ṣiṣẹ́ lórí àtikọ́ ilé Ọlọrun ní Jerusalẹmu, àwọn wolii Ọlọrun mejeeji sì ń ràn wọ́n lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Ẹsira 5

Wo Ẹsira 5:2 ni o tọ