Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹsira 2:69 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n ṣe gẹ́gẹ́ bí agbára wọn ti tó. Wọ́n fi ọọdunrun ó lé mejila (312) kilogiramu wúrà ẹgbẹsan (1,800) kilogiramu fadaka ati ọgọrun-un (100) ẹ̀wù alufaa, ṣe ẹ̀bùn fún ilé OLUWA.

Ka pipe ipin Ẹsira 2

Wo Ẹsira 2:69 ni o tọ