Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 2:22 BIBELI MIMỌ (BM)

O pe àwọn ọ̀tá mi jọ sí mibí ẹni peniyan síbi àjọ̀dún;kò sì sí ẹni tí ó yèní ọjọ́ ibinu rẹ, OLUWA.Ọ̀tá mi pa àwọn ọmọ mi run,àwọn tí mo tọ́, tí mo sì fẹ́ràn.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 2

Wo Ẹkún Jeremaya 2:22 ni o tọ