Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìwà èérí rẹ̀ hàn níbi ìṣẹ́tí aṣọ rẹ̀,kò sì bìkítà fún ìparun tí ń bọ̀.Nítorí náà ni ìṣubú rẹ̀ fi pọ̀, tí kò sì fi ní olùtùnú.Ó ké pe OLUWA pé kí ó ṣíjú wo ìnira òun,nítorí pé ọ̀tá ti borí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:9 ni o tọ