Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkún Jeremaya 1:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Jerusalẹmu ti dẹ́ṣẹ̀ burúkú,nítorí náà ó ti di eléèérí.Àwọn tí wọn ń bu ọlá fún un tẹ́lẹ̀ ti ń kẹ́gàn rẹ̀,nítorí pé wọ́n ti rí ìhòòhò rẹ̀.Òun pàápàá ń kérora, ó sì fi ojú pamọ́.

Ka pipe ipin Ẹkún Jeremaya 1

Wo Ẹkún Jeremaya 1:8 ni o tọ