Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:3 BIBELI MIMỌ (BM)

àjàkálẹ̀ àrùn yóo ti ọwọ́ òun OLUWA wá sórí gbogbo ẹran ọ̀sìn rẹ̀ tí wọ́n wà ní pápá, ati àwọn ẹṣin rẹ̀, ati àwọn kẹ́tẹ́kẹ́tẹ́ rẹ̀, ati àwọn ràkúnmí rẹ̀, ati àwọn agbo mààlúù rẹ̀, ati àwọn agbo aguntan rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:3 ni o tọ