Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Yìnyín ń bọ́, mànàmáná sì ń kọ yànràn ninu yìnyín náà. Yìnyín náà pọ̀ tóbẹ́ẹ̀ gẹ́ẹ́; kò tíì sí irú rẹ̀ rí ní gbogbo ilẹ̀ Ijipti láti ìgbà tí ó ti di orílẹ̀-èdè.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:24 ni o tọ