Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 9:23 BIBELI MIMỌ (BM)

Mose bá na ọ̀pá rẹ̀ sójú ọ̀run, Ọlọrun sì da ààrá ati yìnyín ati iná bo ilẹ̀, Ọlọrun sì rọ̀jò yìnyín sórí ilẹ̀ Ijipti.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 9

Wo Ẹkisodu 9:23 ni o tọ