Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 6:7 BIBELI MIMỌ (BM)

N óo mu yín gẹ́gẹ́ bí eniyan mi, n óo jẹ́ Ọlọrun yín; ẹ óo sì mọ̀ pé èmi ni OLUWA Ọlọrun yín, tí ó fà yín yọ kúrò lábẹ́ ẹrù wúwo tí àwọn ará Ijipti dì rù yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:7 ni o tọ