Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 6:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé, ‘Èmi ni OLUWA, n óo yọ yín jáde kúrò lábẹ́ ẹrù wúwo tí àwọn ará Ijipti dì rù yín, n óo yọ yín kúrò ninu ìgbèkùn wọn, ipá ni n óo sì fi rà yín pada pẹlu ìdájọ́ ńlá.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 6

Wo Ẹkisodu 6:6 ni o tọ