Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:28 BIBELI MIMỌ (BM)

Ninu ẹẹdẹgbẹsan ó lé marundinlọgọrin (1,775) ìwọ̀n ṣekeli fadaka ni ó ti ṣe àwọn ìkọ́ fún àwọn òpó náà, ara rẹ̀ ni ó yọ́ lé àwọn ìbòrí wọn, tí ó sì tún fi ṣe àwọn ọ̀pá tẹ́ẹ́rẹ́tẹ́ẹ́rẹ́ fún aṣọ títa wọn.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:28 ni o tọ