Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 38:27 BIBELI MIMỌ (BM)

Ọgọrun-un talẹnti fadaka yìí ni wọ́n fi ṣe àwọn ìtẹ́lẹ̀ òpó ilé OLUWA ati ìtẹ́lẹ̀ àwọn aṣọ títa. Ọgọrun-un talẹnti ni wọ́n lò láti ṣe ọgọrun-un ìtẹ́lẹ̀, talẹnti kọ̀ọ̀kan fún ìtẹ́lẹ̀ kọ̀ọ̀kan.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 38

Wo Ẹkisodu 38:27 ni o tọ