Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 34:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ ṣọ́ra gidigidi, kí ẹ rí i pé ẹ kò bá àwọn tí wọn ń gbé ilẹ̀ tí ẹ̀ ń lọ dá majẹmu kankan, kí wọn má baà dàbí tàkúté tí a dẹ sí ààrin yín.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:12 ni o tọ