Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 34:11 BIBELI MIMỌ (BM)

“Máa pa àwọn òfin tí mo fún ọ lónìí yìí mọ́. N óo lé àwọn ará Hamori ati àwọn ará Kenaani, àwọn ará Hiti ati àwọn ará Perisi, àwọn ará Hifi ati àwọn ará Jebusi, jáde kúrò níwájú rẹ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 34

Wo Ẹkisodu 34:11 ni o tọ