Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 28:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Oríṣìí òkúta mejila ni yóo wà, orúkọ wọn yóo dàbí orúkọ àwọn ọmọ Israẹli; wọn yóo dàbí èdìdì, wọn yóo sì kọ orúkọ àwọn ẹ̀yà Israẹli mejila sí ara àwọn òkúta mejeejila, òkúta kan fún ẹ̀yà kan.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 28

Wo Ẹkisodu 28:21 ni o tọ