Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 26:1 BIBELI MIMỌ (BM)

“Aṣọ títa mẹ́wàá ni kí o fi ṣe inú àgọ́ mi, kí aṣọ náà jẹ́ aṣọ ọ̀gbọ̀ funfun, kí wọ́n dárà sí aṣọ náà pẹlu àwọ̀ aró, ati àwọ̀ elése àlùkò ati àwọ̀ pupa, kí àwọn tí wọ́n bá mọ iṣẹ́ ọnà ya àwòrán Kerubu sí ara gbogbo aṣọ títa náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 26

Wo Ẹkisodu 26:1 ni o tọ