Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 23:19 BIBELI MIMỌ (BM)

“Ohunkohun tí o bá kọ́ kórè ninu oko rẹ, ilé OLUWA Ọlọrun rẹ ni o gbọdọ̀ mú un wá.“O kò gbọdọ̀ bọ ọmọ ẹran ninu omi wàrà ìyá rẹ̀.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:19 ni o tọ