Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 23:18 BIBELI MIMỌ (BM)

“Nígbà tí o bá fi ohun ẹlẹ́mìí rúbọ sí mi, burẹdi tí o bá fi rúbọ pẹlu rẹ̀ gbọdọ̀ jẹ́ èyí tí kò ní ìwúkàrà ninu, ọ̀rá ẹran tí o bá fi rúbọ sí mi kò sì gbọdọ̀ kù di ọjọ́ keji.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 23

Wo Ẹkisodu 23:18 ni o tọ