Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 2:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Láìpẹ́, ọmọbinrin Farao lọ wẹ̀ ní odò náà, àwọn iranṣẹbinrin rẹ̀ sì ń rìn káàkiri etídò. Ó rí apẹ̀rẹ̀ náà láàrin koríko, ó bá rán iranṣẹbinrin rẹ̀ lọ gbé apẹ̀rẹ̀ náà.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:5 ni o tọ