Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 2:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ní àkókò náà, ọkunrin kan láti inú ẹ̀yà Lefi fẹ́ obinrin kan tí òun náà jẹ́ ẹ̀yà Lefi.

2. Obinrin náà lóyún, ó sì bí ọmọkunrin kan. Nígbà tí ó rí i pé ọmọ náà jẹ́ arẹwà, ó gbé e pamọ́ fún oṣù mẹta.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2