Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 2:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí kò lè gbé e pamọ́ mọ́, ó fi koríko kan tí ó dàbí èèsún ṣe apẹ̀rẹ̀ kan, ó fi oje igi ati ọ̀dà ilẹ̀ rẹ́ ẹ, ó gbé ọmọ náà sinu rẹ̀, ó sì gbé apẹ̀rẹ̀ náà sí ààrin koríko lẹ́bàá odò.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 2

Wo Ẹkisodu 2:3 ni o tọ