Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 17:5 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA bá sọ fún Mose pé, “Mú ninu àwọn àgbààgbà ilẹ̀ Israẹli lọ́wọ́, kí ẹ jọ la ààrin àwọn eniyan náà kọjá, kí o sì mú ọ̀pá tí o fi lu odò Naili lọ́wọ́, bí o bá ti ń lọ.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 17

Wo Ẹkisodu 17:5 ni o tọ