Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí Ọlọrun bá mu yín wá sí ilẹ̀ àwọn ará Kenaani ati ti àwọn ará Hiti, ati ti àwọn ará Amori, ati ti àwọn ará Hifi, ati ti àwọn ará Jebusi, tí ó ti búra fún àwọn baba yín pé òun yóo fi fún yín, tí ó kún fún wàrà ati oyin, ẹ óo máa ṣe ìsìn yìí ninu oṣù yìí lọdọọdun.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 13

Wo Ẹkisodu 13:5 ni o tọ