Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ẹkisodu 10:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọn yóo rọ́ kún gbogbo ààfin rẹ ati ilé gbogbo àwọn ẹmẹ̀wà rẹ ati ilé gbogbo àwọn ará Ijipti, àwọn eṣú náà yóo burú ju ohunkohun tí àwọn baba ati àwọn baba ńlá yín ti rí rí lọ, láti ọjọ́ tí wọ́n ti dáyé títí di òní olónìí.” Mose bá yipada kúrò níwájú Farao.

Ka pipe ipin Ẹkisodu 10

Wo Ẹkisodu 10:6 ni o tọ